-
Jóòbù 2:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Níkẹyìn, ìyàwó rẹ̀ sọ fún un pé: “Ṣé pé o ò tíì fi ìwà títọ́ rẹ sílẹ̀? Sọ̀rọ̀ òdì sí Ọlọ́run, kí o sì kú!” 10 Àmọ́ Jóòbù sọ fún un pé: “Ò ń sọ̀rọ̀ bí ọ̀kan lára àwọn obìnrin tí kò nírònú. Tí a bá gba ohun rere lọ́wọ́ Ọlọ́run tòótọ́, ṣé kò yẹ ká tún gba ohun búburú?”+ Nínú gbogbo ohun tó ṣẹlẹ̀ yìí, Jóòbù kò fi ẹnu rẹ̀ dẹ́ṣẹ̀.+
-