-
Hábákúkù 1:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Kí nìdí tí o fi ń jẹ́ kí ohun búburú ṣẹlẹ̀ níṣojú mi?
Kí sì nìdí tí o fi fàyè gba ìnilára?
Kí nìdí tí ìparun àti ìwà ipá fi ń ṣẹlẹ̀ níṣojú mi?
Kí sì nìdí tí ìjà àti aáwọ̀ fi wà káàkiri?
-