- 
	                        
            
            Àìsáyà 40:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        23 Ó ń sọ àwọn aláṣẹ di ẹni tí kò já mọ́ nǹkan kan, Ó sì ń sọ àwọn adájọ́* ayé di ohun tí kò sí rárá. 
 
- 
                                        
23 Ó ń sọ àwọn aláṣẹ di ẹni tí kò já mọ́ nǹkan kan,
Ó sì ń sọ àwọn adájọ́* ayé di ohun tí kò sí rárá.