Jóòbù 24:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ìyá rẹ̀* máa gbàgbé rẹ̀; ìdin máa fi ṣe oúnjẹ. Wọn ò ní rántí rẹ̀ mọ́.+ A sì máa ṣẹ́ àìṣòdodo bí igi.
20 Ìyá rẹ̀* máa gbàgbé rẹ̀; ìdin máa fi ṣe oúnjẹ. Wọn ò ní rántí rẹ̀ mọ́.+ A sì máa ṣẹ́ àìṣòdodo bí igi.