Hábákúkù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà, báwo ló ṣe máa pẹ́ tó tí màá fi ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́ àmọ́ tí o kò gbọ́?+ Báwo ló ṣe máa pẹ́ tó tí màá fi ké pè ọ́ pé kí o gbà mí lọ́wọ́ ìwà ipá àmọ́ tí o kò dá sí i?*+
2 Jèhófà, báwo ló ṣe máa pẹ́ tó tí màá fi ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́ àmọ́ tí o kò gbọ́?+ Báwo ló ṣe máa pẹ́ tó tí màá fi ké pè ọ́ pé kí o gbà mí lọ́wọ́ ìwà ipá àmọ́ tí o kò dá sí i?*+