-
Ìsíkíẹ́lì 27:30, 31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Wọ́n á gbé ohùn wọn sókè, wọ́n á sì sunkún kíkan nítorí rẹ+
Bí wọ́n ṣe ń da eruku sórí ara wọn, tí wọ́n sì ń yíra nínú eérú.
-