- 
	                        
            
            Jeremáyà 22:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        13 Ẹni tó ń fi àìṣòdodo kọ́ ilé rẹ̀ ti gbé! Tó ń fi àìṣẹ̀tọ́ kọ́ àwọn yàrá òkè rẹ̀, Tó ń mú kí ọmọnìkejì rẹ̀ sìn ín láìgba nǹkan kan, Tí kò sì fún un ní owó iṣẹ́ rẹ̀;+ 
 
-