Oníwàásù 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mo tún fiyè sí gbogbo ìwà ìnilára tó ń lọ lábẹ́ ọ̀run.* Mo rí omijé àwọn tí wọ́n ń ni lára, kò sí ẹni tó máa tù wọ́n nínú.+ Agbára wà lọ́wọ́ àwọn tó ń ni wọ́n lára, kò sì sí ẹni tó máa tù wọ́n nínú.
4 Mo tún fiyè sí gbogbo ìwà ìnilára tó ń lọ lábẹ́ ọ̀run.* Mo rí omijé àwọn tí wọ́n ń ni lára, kò sí ẹni tó máa tù wọ́n nínú.+ Agbára wà lọ́wọ́ àwọn tó ń ni wọ́n lára, kò sì sí ẹni tó máa tù wọ́n nínú.