Òwe 7:8-10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó gba ojú ọ̀nà tó wà nítòsí ìyànà ilé obìnrin náà kọjá,Ó sì rìn lọ sí ọ̀nà ilé obìnrin náà 9 Ní ìrọ̀lẹ́, ní àṣálẹ́,+Nígbà tí ilẹ̀ ń ṣú, tí òkùnkùn sì ń kùn. 10 Ni mo bá rí obìnrin kan tó wá pàdé rẹ̀,Ó múra bí* aṣẹ́wó,+ ó ní ọkàn àrékérekè.
8 Ó gba ojú ọ̀nà tó wà nítòsí ìyànà ilé obìnrin náà kọjá,Ó sì rìn lọ sí ọ̀nà ilé obìnrin náà 9 Ní ìrọ̀lẹ́, ní àṣálẹ́,+Nígbà tí ilẹ̀ ń ṣú, tí òkùnkùn sì ń kùn. 10 Ni mo bá rí obìnrin kan tó wá pàdé rẹ̀,Ó múra bí* aṣẹ́wó,+ ó ní ọkàn àrékérekè.