Jeremáyà 20:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ègún ni fún ọjọ́ tí wọ́n bí mi! Kí ọjọ́ tí ìyá mi bí mi má gba ìbùkún! + 15 Ègún ni fún ọkùnrin tó mú ìròyìn ayọ̀ wá fún bàbá mi pé: “Ìyàwó rẹ ti bímọ, ọkùnrin ló bí!” Tó mú inú rẹ̀ dùn gidigidi.
14 Ègún ni fún ọjọ́ tí wọ́n bí mi! Kí ọjọ́ tí ìyá mi bí mi má gba ìbùkún! + 15 Ègún ni fún ọkùnrin tó mú ìròyìn ayọ̀ wá fún bàbá mi pé: “Ìyàwó rẹ ti bímọ, ọkùnrin ló bí!” Tó mú inú rẹ̀ dùn gidigidi.