Sáàmù 139:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Tí mo bá lọ sọ́run, wàá wà níbẹ̀,Tí mo bá sì tẹ́ ibùsùn mi sínú Isà Òkú,* wò ó! wàá ti wà níbẹ̀.+ Hébérù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+
13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+