Jóòbù 9:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Òun nìkan na ọ̀run jáde,+Ó sì ń rìn lórí ìgbì tó ga lórí òkun.+ Sáàmù 104:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 O fi ìmọ́lẹ̀+ bora bí aṣọ;O na ọ̀run bí aṣọ àgọ́.+ Àìsáyà 42:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ohun tí Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́, sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run àti Atóbilọ́lá tó nà án jáde,+Ẹni tó tẹ́ ayé àti èso rẹ̀,+Ẹni tó fún àwọn èèyàn inú rẹ̀ ní èémí,+Tó sì fún àwọn tó ń rìn lórí rẹ̀ ní ẹ̀mí:+
5 Ohun tí Jèhófà, Ọlọ́run tòótọ́, sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run àti Atóbilọ́lá tó nà án jáde,+Ẹni tó tẹ́ ayé àti èso rẹ̀,+Ẹni tó fún àwọn èèyàn inú rẹ̀ ní èémí,+Tó sì fún àwọn tó ń rìn lórí rẹ̀ ní ẹ̀mí:+