Àìsáyà 10:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí lẹ máa ṣe ní ọjọ́ ìjíhìn,*+Tí ìparun bá wá láti ọ̀nà jíjìn?+ Ta lẹ máa sá lọ bá pé kó ràn yín lọ́wọ́,+Ibo lẹ sì máa fi ọrọ̀* yín sí? Émọ́sì 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Asáré tete kò ní rí ibi sá sí,+Alágbára kò ní lókun mọ́,Kò sì ní sí jagunjagun tó máa lè gba ẹ̀mí* ara rẹ̀ là.
3 Kí lẹ máa ṣe ní ọjọ́ ìjíhìn,*+Tí ìparun bá wá láti ọ̀nà jíjìn?+ Ta lẹ máa sá lọ bá pé kó ràn yín lọ́wọ́,+Ibo lẹ sì máa fi ọrọ̀* yín sí?
14 Asáré tete kò ní rí ibi sá sí,+Alágbára kò ní lókun mọ́,Kò sì ní sí jagunjagun tó máa lè gba ẹ̀mí* ara rẹ̀ là.