Òwe 8:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí ọgbọ́n sàn ju iyùn* lọ;Kò sí ohun ṣíṣeyebíye míì tí a lè fi wé e. Òwe 20:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Wúrà wà, ọ̀pọ̀ iyùn* sì wà,Àmọ́ ètè ìmọ̀ jẹ́ ohun tó ṣeyebíye.+