Òwe 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ojú Jèhófà wà níbi gbogbo,Ó ń ṣọ́ ẹni burúkú àti ẹni rere.+ Sekaráyà 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ta ló pẹ̀gàn ọjọ́ tí nǹkan bẹ̀rẹ̀ wẹ́rẹ́?*+ Inú wọn á dùn, wọ́n á sì rí okùn ìwọ̀n* ní ọwọ́ Serubábélì. Àwọn méje yìí ni ojú Jèhófà, tó ń wò káàkiri ayé.”+ 1 Pétérù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí ojú Jèhófà* wà lára àwọn olódodo, etí rẹ̀ sì ṣí sí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn;+ àmọ́ Jèhófà* kọjú ìjà sí àwọn tó ń ṣe ohun búburú.”+
10 Ta ló pẹ̀gàn ọjọ́ tí nǹkan bẹ̀rẹ̀ wẹ́rẹ́?*+ Inú wọn á dùn, wọ́n á sì rí okùn ìwọ̀n* ní ọwọ́ Serubábélì. Àwọn méje yìí ni ojú Jèhófà, tó ń wò káàkiri ayé.”+
12 Nítorí ojú Jèhófà* wà lára àwọn olódodo, etí rẹ̀ sì ṣí sí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn;+ àmọ́ Jèhófà* kọjú ìjà sí àwọn tó ń ṣe ohun búburú.”+