Òwe 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara rẹ.+ Bẹ̀rù Jèhófà kí o sì yẹra fún ibi.