Nehemáyà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Gbogbo àwọn èèyàn náà kóra jọ ní ìṣọ̀kan sí gbàgede ìlú tó wà níwájú Ẹnubodè Omi,+ wọ́n sì sọ fún Ẹ́sírà+ adàwékọ* pé kó mú ìwé Òfin Mósè+ wá, èyí tí Jèhófà pa láṣẹ fún Ísírẹ́lì.+
8 Gbogbo àwọn èèyàn náà kóra jọ ní ìṣọ̀kan sí gbàgede ìlú tó wà níwájú Ẹnubodè Omi,+ wọ́n sì sọ fún Ẹ́sírà+ adàwékọ* pé kó mú ìwé Òfin Mósè+ wá, èyí tí Jèhófà pa láṣẹ fún Ísírẹ́lì.+