Òwe 29:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ̀tọ́ àwọn aláìní jẹ olódodo lọ́kàn,+Àmọ́ ẹni burúkú kì í ronú irú nǹkan bẹ́ẹ̀.+