Jẹ́nẹ́sísì 25:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ábúráhámù mí èémí ìkẹyìn, ó sì kú, ó darúgbó, ayé rẹ̀ sì dára, wọ́n wá kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀.* 2 Àwọn Ọba 22:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ìdí nìyẹn tí màá fi kó ọ jọ sọ́dọ̀ àwọn baba ńlá rẹ,* a ó tẹ́ ọ sínú sàréè rẹ ní àlàáfíà, ojú rẹ ò ní rí gbogbo àjálù tí màá mú bá ibí yìí.’”’” Lẹ́yìn náà, wọ́n mú èsì náà wá fún ọba.
8 Ábúráhámù mí èémí ìkẹyìn, ó sì kú, ó darúgbó, ayé rẹ̀ sì dára, wọ́n wá kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀.*
20 Ìdí nìyẹn tí màá fi kó ọ jọ sọ́dọ̀ àwọn baba ńlá rẹ,* a ó tẹ́ ọ sínú sàréè rẹ ní àlàáfíà, ojú rẹ ò ní rí gbogbo àjálù tí màá mú bá ibí yìí.’”’” Lẹ́yìn náà, wọ́n mú èsì náà wá fún ọba.