Oníwàásù 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó sàn láti lọ sí ilé ọ̀fọ̀ ju láti lọ sí ilé àsè,+ torí pé ìyẹn ni òpin gbogbo èèyàn, ó sì yẹ kí àwọn alààyè fi sọ́kàn.
2 Ó sàn láti lọ sí ilé ọ̀fọ̀ ju láti lọ sí ilé àsè,+ torí pé ìyẹn ni òpin gbogbo èèyàn, ó sì yẹ kí àwọn alààyè fi sọ́kàn.