-
Nọ́ńbà 12:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Jèhófà dá Mósè lóhùn pé: “Tó bá jẹ́ bàbá rẹ̀ ló tutọ́ sí i lójú, ǹjẹ́ ọjọ́ méje kọ́ lojú fi máa tì í? Ẹ lọ sé e mọ́ ẹ̀yìn ibùdó+ fún ọjọ́ méje, lẹ́yìn náà, kí ẹ jẹ́ kó wọlé.”
-
-
Àìsáyà 50:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Mi ò fi ojú mi pa mọ́ fún àwọn ohun tó ń dójú tini àti itọ́.+
-