-
Jóòbù 16:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Mo ti gbọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan báyìí rí.
Olùtùnú tó ń dani láàmú ni gbogbo yín!+
-
-
Sáàmù 69:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Nítorí ẹni tí o ti lù ni wọ́n ń lépa,
Wọ́n sì ń sọ nípa ìrora àwọn tí o ṣe léṣe.
-