Jóòbù 10:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Tí mo bá jẹ̀bi, mo gbé! Tí mi ò bá tiẹ̀ mọwọ́ mẹsẹ̀, mi ò lè gbé orí mi sókè,+Torí ìtìjú àti ìyà+ ti bò mí mọ́lẹ̀.
15 Tí mo bá jẹ̀bi, mo gbé! Tí mi ò bá tiẹ̀ mọwọ́ mẹsẹ̀, mi ò lè gbé orí mi sókè,+Torí ìtìjú àti ìyà+ ti bò mí mọ́lẹ̀.