ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 2:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Jóòbù wá mú àfọ́kù ìkòkò, ó sì fi ń họ ara rẹ̀, ó wá jókòó sínú eérú.+

  • Jóòbù 2:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Wọ́n sì jókòó sílẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ fún ọ̀sán méje àti òru méje. Ẹnì kankan ò bá a sọ̀rọ̀, torí wọ́n rí i pé ìrora rẹ̀ pọ̀ gan-an.+

  • Jóòbù 7:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Nígbà tí mo dùbúlẹ̀, mo béèrè pé, ‘Ìgbà wo ni màá dìde?’+

      Àmọ́ bí òru náà ṣe ń falẹ̀, ṣe ni mò ń yí kiri títí ilẹ̀ fi mọ́.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́