Sáàmù 146:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀mí* rẹ̀ jáde lọ, ó pa dà sínú ilẹ̀;+Ọjọ́ yẹn gan-an ni èrò inú rẹ̀ ṣègbé.+ Oníwàásù 9:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ohunkóhun tí ọwọ́ rẹ bá rí láti ṣe, fi gbogbo agbára rẹ ṣe é, nítorí pé kò sí iṣẹ́ tàbí èrò tàbí ìmọ̀ tàbí ọgbọ́n nínú Isà Òkú,*+ ibi tí ìwọ ń lọ. Àìsáyà 57:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Olódodo ṣègbé,Àmọ́ ẹnì kankan ò fi sọ́kàn. Àwọn olóòótọ́ èèyàn ti lọ,*+Ẹnì kankan ò sì fòye mọ̀ pé olódodo ti lọTorí* àjálù náà. 2 Ó wọnú àlàáfíà. Wọ́n sinmi lórí ibùsùn wọn,* gbogbo àwọn tó ń rìn lọ́nà títọ́.
10 Ohunkóhun tí ọwọ́ rẹ bá rí láti ṣe, fi gbogbo agbára rẹ ṣe é, nítorí pé kò sí iṣẹ́ tàbí èrò tàbí ìmọ̀ tàbí ọgbọ́n nínú Isà Òkú,*+ ibi tí ìwọ ń lọ.
57 Olódodo ṣègbé,Àmọ́ ẹnì kankan ò fi sọ́kàn. Àwọn olóòótọ́ èèyàn ti lọ,*+Ẹnì kankan ò sì fòye mọ̀ pé olódodo ti lọTorí* àjálù náà. 2 Ó wọnú àlàáfíà. Wọ́n sinmi lórí ibùsùn wọn,* gbogbo àwọn tó ń rìn lọ́nà títọ́.