-
Jóòbù 7:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Tí mo bá ṣẹ̀, ṣé mo lè ṣe ọ́ níbi, ìwọ Ẹni tó ń kíyè sí aráyé?+
Kí ló dé tí o dájú sọ mí?
Àbí mo ti di ìnira fún ọ ni?
-
-
Jóòbù 19:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Nígbà náà, kí ẹ mọ̀ pé Ọlọ́run ló ṣì mí lọ́nà,
Ó sì ti fi àwọ̀n tó fi ń dọdẹ mú mi.
-