-
Jóòbù 13:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ṣé o máa fẹ́ dẹ́rù ba ewé tí afẹ́fẹ́ ń gbé kiri ni,
Àbí o fẹ́ máa sáré lé àgékù pòròpórò tó ti gbẹ?