-
Jẹ́nẹ́sísì 19:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Àwọn áńgẹ́lì méjì náà dé Sódómù ní alẹ́, Lọ́ọ̀tì sì jókòó sí ẹnubodè Sódómù. Nígbà tí Lọ́ọ̀tì rí wọn, ó dìde lọ pàdé wọn, ó sì tẹrí ba mọ́lẹ̀.+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 19:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Àmọ́ kò fi wọ́n lọ́rùn sílẹ̀, títí wọ́n fi tẹ̀ lé e lọ sílé rẹ̀. Ó se àsè fún wọn, ó yan búrẹ́dì aláìwú, wọ́n sì jẹun.
-