-
Jóòbù 12:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Tó bá ya nǹkan lulẹ̀, kò ṣeé tún kọ́;+
Tó bá ti nǹkan pa, èèyàn kankan ò lè ṣí i.
-
-
Jóòbù 19:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ó ti fi ògiri olókùúta dí ọ̀nà mi, mi ò sì lè kọjá;
Ó ti fi òkùnkùn+ bo àwọn òpópónà mi.
-