- 
	                        
            
            Jẹ́nẹ́sísì 22:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        20 Lẹ́yìn èyí, wọ́n ròyìn fún Ábúráhámù pé: “Mílíkà náà ti bí àwọn ọmọ fún Náhórì arákùnrin+ rẹ: 21 Úsì ni àkọ́bí rẹ̀, Búsì ni àbúrò àti Kémúélì bàbá Árámù, 
 
-