Sáàmù 102:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Eérú ni mo fi ń ṣe oúnjẹ jẹ,+Omijé sì ti dà pọ̀ mọ́ ohun tí mò ń mu,+10 Nítorí ìbínú rẹ àti ìrunú rẹ,O gbé mi sókè kí o lè jù mí sí ẹ̀gbẹ́ kan.
9 Eérú ni mo fi ń ṣe oúnjẹ jẹ,+Omijé sì ti dà pọ̀ mọ́ ohun tí mò ń mu,+10 Nítorí ìbínú rẹ àti ìrunú rẹ,O gbé mi sókè kí o lè jù mí sí ẹ̀gbẹ́ kan.