1 Tímótì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Má ṣe fi ọ̀rọ̀ líle bá àgbà ọkùnrin wí.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, ṣe ni kí o pàrọwà fún un bíi bàbá, pàrọwà fún àwọn ọ̀dọ́kùnrin bí ọmọ ìyá, 1 Pétérù 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, kí ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin máa tẹrí ba fún àwọn àgbà ọkùnrin.*+ Àmọ́ kí gbogbo yín gbé ìrẹ̀lẹ̀* wọ̀* nínú àjọṣe yín, torí Ọlọ́run dojú ìjà kọ àwọn agbéraga, àmọ́ ó ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí hàn sí àwọn onírẹ̀lẹ̀.+
5 Má ṣe fi ọ̀rọ̀ líle bá àgbà ọkùnrin wí.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, ṣe ni kí o pàrọwà fún un bíi bàbá, pàrọwà fún àwọn ọ̀dọ́kùnrin bí ọmọ ìyá,
5 Bákan náà, kí ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin máa tẹrí ba fún àwọn àgbà ọkùnrin.*+ Àmọ́ kí gbogbo yín gbé ìrẹ̀lẹ̀* wọ̀* nínú àjọṣe yín, torí Ọlọ́run dojú ìjà kọ àwọn agbéraga, àmọ́ ó ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí hàn sí àwọn onírẹ̀lẹ̀.+