Mátíù 12:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ẹ̀yin ọmọ paramọ́lẹ̀,+ báwo lẹ ṣe lè sọ àwọn ohun tó dáa nígbà tó jẹ́ pé ẹni burúkú ni yín? Torí lára ọ̀pọ̀ nǹkan tó wà nínú ọkàn ni ẹnu ń sọ.+ Lúùkù 6:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ẹni rere máa ń mú ohun rere jáde látinú ìṣúra rere tó wà nínú ọkàn rẹ̀, àmọ́ ẹni burúkú máa ń mú ohun burúkú jáde látinú ìṣúra burúkú rẹ̀; torí lára ọ̀pọ̀ nǹkan tó wà nínú ọkàn ni ẹnu rẹ̀ ń sọ.+
34 Ẹ̀yin ọmọ paramọ́lẹ̀,+ báwo lẹ ṣe lè sọ àwọn ohun tó dáa nígbà tó jẹ́ pé ẹni burúkú ni yín? Torí lára ọ̀pọ̀ nǹkan tó wà nínú ọkàn ni ẹnu ń sọ.+
45 Ẹni rere máa ń mú ohun rere jáde látinú ìṣúra rere tó wà nínú ọkàn rẹ̀, àmọ́ ẹni burúkú máa ń mú ohun burúkú jáde látinú ìṣúra burúkú rẹ̀; torí lára ọ̀pọ̀ nǹkan tó wà nínú ọkàn ni ẹnu rẹ̀ ń sọ.+