2 Àwọn Ọba 5:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ni ó bá lọ síbẹ̀, ó sì ri* ara rẹ̀ bọ inú odò Jọ́dánì ní ìgbà méje gẹ́gẹ́ bí èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ ti sọ.+ Lẹ́yìn náà, ara rẹ̀ pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀, ó rí bí ara ọmọ kékeré,+ ó sì mọ́.+
14 Ni ó bá lọ síbẹ̀, ó sì ri* ara rẹ̀ bọ inú odò Jọ́dánì ní ìgbà méje gẹ́gẹ́ bí èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ ti sọ.+ Lẹ́yìn náà, ara rẹ̀ pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀, ó rí bí ara ọmọ kékeré,+ ó sì mọ́.+