- 
	                        
            
            Diutarónómì 34:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        7 Ẹni ọgọ́fà (120) ọdún ni Mósè nígbà tó kú.+ Ojú rẹ̀ ò di bàìbàì, agbára rẹ̀ ò sì dín kù. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jóòbù 42:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        16 Lẹ́yìn èyí, Jóòbù lo ogóje (140) ọdún sí i láyé, ó sì rí àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀, dé ìran kẹrin. 
 
-