Sáàmù 89:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Òdodo àti ìdájọ́ òdodo ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ;+Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ dúró níwájú rẹ.+ Sáàmù 97:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìkùukùu àti ìṣúdùdù tó kàmàmà yí i ká;+Òtítọ́ àti ìdájọ́ òdodo ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ̀.+ Sáàmù 99:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọba alágbára ńlá tó nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo ni.+ O ti fìdí ohun tí ó tọ́ múlẹ̀ ṣinṣin. O ti mú kí ìdájọ́ òdodo+ àti òtítọ́ wà ní Jékọ́bù. Róòmù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí kò sí ojúsàájú lọ́dọ̀ Ọlọ́run.+
4 Ọba alágbára ńlá tó nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo ni.+ O ti fìdí ohun tí ó tọ́ múlẹ̀ ṣinṣin. O ti mú kí ìdájọ́ òdodo+ àti òtítọ́ wà ní Jékọ́bù.