Òwe 22:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Má ja tálákà lólè torí pé kò ní lọ́wọ́,+Má sì fojú aláìní gbolẹ̀ ní ẹnubodè,+ Émọ́sì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí mo mọ bí ìdìtẹ̀* yín ṣe pọ̀ tóÀti bí ẹ̀ṣẹ̀ yín ṣe pọ̀ tóẸ̀ ń dààmú àwọn olódodo,Ẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀,*Ẹ sì ń fi ẹ̀tọ́ àwọn aláìní dù wọ́n ní ẹnubodè.+
22 Má ja tálákà lólè torí pé kò ní lọ́wọ́,+Má sì fojú aláìní gbolẹ̀ ní ẹnubodè,+ Émọ́sì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí mo mọ bí ìdìtẹ̀* yín ṣe pọ̀ tóÀti bí ẹ̀ṣẹ̀ yín ṣe pọ̀ tóẸ̀ ń dààmú àwọn olódodo,Ẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀,*Ẹ sì ń fi ẹ̀tọ́ àwọn aláìní dù wọ́n ní ẹnubodè.+
12 Nítorí mo mọ bí ìdìtẹ̀* yín ṣe pọ̀ tóÀti bí ẹ̀ṣẹ̀ yín ṣe pọ̀ tóẸ̀ ń dààmú àwọn olódodo,Ẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀,*Ẹ sì ń fi ẹ̀tọ́ àwọn aláìní dù wọ́n ní ẹnubodè.+