Sáàmù 28:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí pé wọn kò fiyè sí àwọn iṣẹ́ Jèhófà,+Wọn ò sì ka iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ sí.+ Yóò ya wọ́n lulẹ̀, kò sì ní gbé wọn ró.
5 Nítorí pé wọn kò fiyè sí àwọn iṣẹ́ Jèhófà,+Wọn ò sì ka iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ sí.+ Yóò ya wọ́n lulẹ̀, kò sì ní gbé wọn ró.