Jóòbù 13:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ó máa wá di ìgbàlà mi,+Torí ẹni tí kò mọ Ọlọ́run* kò lè wá síwájú rẹ̀.+ Jóòbù 27:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí ìrètí wo ni ẹni tí kò mọ Ọlọ́run* ní tó bá pa run,+Tí Ọlọ́run bá gba ẹ̀mí* rẹ̀?