Sáàmù 68:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ti Ọlọ́run ni agbára.+ Ọlá ńlá rẹ̀ wà lórí Ísírẹ́lìÀti okun rẹ̀ lójú ọ̀run.*