Sáàmù 94:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Aláyọ̀ ni ẹni tí o tọ́ sọ́nà, Jáà,+Ẹni tí o kọ́ ní òfin rẹ,+ Àìsáyà 48:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà rẹ, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó ń kọ́ ọ kí o lè ṣe ara rẹ láǹfààní,*+Ẹni tó ń jẹ́ kí o mọ ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+
12 Aláyọ̀ ni ẹni tí o tọ́ sọ́nà, Jáà,+Ẹni tí o kọ́ ní òfin rẹ,+ Àìsáyà 48:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà rẹ, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó ń kọ́ ọ kí o lè ṣe ara rẹ láǹfààní,*+Ẹni tó ń jẹ́ kí o mọ ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+
17 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà rẹ, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó ń kọ́ ọ kí o lè ṣe ara rẹ láǹfààní,*+Ẹni tó ń jẹ́ kí o mọ ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+