Òwe 1:28, 29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ní àkókò yẹn, wọ́n á máa pè mí, àmọ́ mi ò ní dáhùn;Wọ́n á máa fi ìtara wá mi, àmọ́ wọn ò ní rí mi,+29 Torí wọ́n kórìíra ìmọ̀,+Wọn ò sì bẹ̀rù Jèhófà.+ 1 Pétérù 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, kí ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin máa tẹrí ba fún àwọn àgbà ọkùnrin.*+ Àmọ́ kí gbogbo yín gbé ìrẹ̀lẹ̀* wọ̀* nínú àjọṣe yín, torí Ọlọ́run dojú ìjà kọ àwọn agbéraga, àmọ́ ó ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí hàn sí àwọn onírẹ̀lẹ̀.+
28 Ní àkókò yẹn, wọ́n á máa pè mí, àmọ́ mi ò ní dáhùn;Wọ́n á máa fi ìtara wá mi, àmọ́ wọn ò ní rí mi,+29 Torí wọ́n kórìíra ìmọ̀,+Wọn ò sì bẹ̀rù Jèhófà.+
5 Bákan náà, kí ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin máa tẹrí ba fún àwọn àgbà ọkùnrin.*+ Àmọ́ kí gbogbo yín gbé ìrẹ̀lẹ̀* wọ̀* nínú àjọṣe yín, torí Ọlọ́run dojú ìjà kọ àwọn agbéraga, àmọ́ ó ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí hàn sí àwọn onírẹ̀lẹ̀.+