Sáàmù 24:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ta ni Ọba ológo yìí? Jèhófà ni, ẹni tó ní okun àti agbára,+Jèhófà, akin lójú ogun.+ Sáàmù 99:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọba alágbára ńlá tó nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo ni.+ O ti fìdí ohun tí ó tọ́ múlẹ̀ ṣinṣin. O ti mú kí ìdájọ́ òdodo+ àti òtítọ́ wà ní Jékọ́bù. Jeremáyà 32:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 ìwọ Ẹni tó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹgbẹẹgbẹ̀rún, àmọ́ tí ò ń bẹ ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba wò lára* àwọn ọmọ tí wọ́n fi sílẹ̀,+ ìwọ Ọlọ́run tòótọ́, tí o jẹ́ Ẹni ńlá àti alágbára ńlá, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ.
4 Ọba alágbára ńlá tó nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo ni.+ O ti fìdí ohun tí ó tọ́ múlẹ̀ ṣinṣin. O ti mú kí ìdájọ́ òdodo+ àti òtítọ́ wà ní Jékọ́bù.
18 ìwọ Ẹni tó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹgbẹẹgbẹ̀rún, àmọ́ tí ò ń bẹ ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba wò lára* àwọn ọmọ tí wọ́n fi sílẹ̀,+ ìwọ Ọlọ́run tòótọ́, tí o jẹ́ Ẹni ńlá àti alágbára ńlá, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ.