Jeremáyà 26:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí náà, ẹ tún ọ̀nà àti ìwà yín ṣe, ẹ sì ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà sì máa pèrò dà* lórí àjálù tó ti sọ pé òun máa mú bá yín.+
13 Torí náà, ẹ tún ọ̀nà àti ìwà yín ṣe, ẹ sì ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà sì máa pèrò dà* lórí àjálù tó ti sọ pé òun máa mú bá yín.+