Jóòbù 34:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wọ́n lè kú lójijì,+ láàárín òru;+Wọ́n gbọ̀n rìrì, wọ́n sì gbẹ́mìí mì;A mú àwọn alágbára pàápàá kúrò, àmọ́ kì í ṣe iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn.+ Sáàmù 33:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ọ̀pọ̀ ọmọ ogun kọ́ ló ń gba ọba là;+Agbára ńlá kò sì lè gba ẹni tó ni ín sílẹ̀.+ Òwe 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọrọ̀* kò ní ṣeni láǹfààní ní ọjọ́ ìbínú ńlá,+Àmọ́ òdodo ló ń gbani lọ́wọ́ ikú.+
20 Wọ́n lè kú lójijì,+ láàárín òru;+Wọ́n gbọ̀n rìrì, wọ́n sì gbẹ́mìí mì;A mú àwọn alágbára pàápàá kúrò, àmọ́ kì í ṣe iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn.+