Sáàmù 92:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn iṣẹ́ rẹ mà tóbi o, Jèhófà!+ Èrò rẹ jinlẹ̀ gidigidi!+ Sáàmù 104:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àwọn iṣẹ́ rẹ mà pọ̀ o, Jèhófà!+ Gbogbo wọn lo fi ọgbọ́n ṣe.+ Ayé kún fún àwọn ohun tí o ṣe.