1 Kíróníkà 16:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ògo àti ọlá ńlá*+ wà pẹ̀lú rẹ̀;Agbára àti ìdùnnú wà ní ibi tó ń gbé.+ Sáàmù 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà Olúwa wa, orúkọ rẹ mà níyì ní gbogbo ayé o;O ti gbé ògo rẹ ga, kódà ó ga ju ọ̀run lọ!*+