Sáàmù 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí olódodo ni Jèhófà;+ ó nífẹ̀ẹ́ àwọn iṣẹ́ òdodo.+ Àwọn adúróṣinṣin yóò rí ojú* rẹ̀.+ Sáàmù 71:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọlọ́run, òdodo rẹ ga dé òkè;+O ti ṣe àwọn ohun ńlá;Ọlọ́run, ta ló dà bí rẹ?+