-
Ẹ́kísódù 9:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Yìnyín bọ́, iná sì ń kọ mànà láàárín yìnyín náà. Yìnyín náà pọ̀ gan-an; kò sí irú rẹ̀ rí nílẹ̀ náà látìgbà tí Íjíbítì ti di orílẹ̀-èdè.+
-
-
Ìsíkíẹ́lì 13:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 “Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Màá fi ìbínú mú kí ìjì líle jà, màá fi ìrunú rọ àrọ̀ọ̀rọ̀dá òjò, ìbínú tó le ni màá sì fi rọ yìnyín láti pa á run.
-