ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 12:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ni Sámúẹ́lì bá ké pe Jèhófà, Jèhófà wá sán ààrá, ó sì rọ òjò ní ọjọ́ yẹn, tí gbogbo àwọn èèyàn náà fi bẹ̀rù Jèhófà àti Sámúẹ́lì gidigidi.

  • Àìsáyà 30:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ó máa rọ òjò sí ohun tí o gbìn sínú ilẹ̀,+ oúnjẹ tí ilẹ̀ bá sì mú jáde máa pọ̀ rẹpẹtẹ, ó sì máa lọ́ràá.*+ Ní ọjọ́ yẹn, ẹran ọ̀sìn rẹ máa jẹko ní àwọn pápá tó fẹ̀.+

  • Jeremáyà 5:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Wọn ò sì sọ lọ́kàn wọn pé:

      “Ẹ jẹ́ ká bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run wa,

      Ẹni tó ń fúnni ní òjò ní àsìkò rẹ̀,

      Òjò ìgbà ìkórè àti òjò ìgbà ìrúwé,

      Ẹni tí kò jẹ́ kí àwọn ọ̀sẹ̀ ìkórè wa yẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́